Ijinigbe: Gomina Makinde gbe foomu ati gba awon ode Amotekun inugbo jade 

Ijinigbe: Gomina Makinde gbe foomu ati gba awon ode Amotekun inugbo jade 

 

Khalid ABRAHAM

 

Gomina ipinle Oyo Onimo ero Oluseyi Makinde ti fi ohunte lu gbigba awon iko amotekun tuntun, papaajulo awon ode ti yio ma so inu igbo (Forest Rangers) lati dekun iwa ijinigbe ati lilo igbo fun awon iwa ti ko to ni ipinle yi.

Advertisement

Oludari Amotekun ni ipinle oyo arakunrin Olayinka Olayanju lo so eyi di mimo ninu atejade kan to fi ranse si awon oniroyin ni ilu ibadan ni ojo Satide.

 

Olayanju, eni ti o to feyin ti ni ile ise ologun lori le ede naijiria so wipe eni to nife lati se ise naa yioo lo si ori ate iroyin Ipinle Oyo www.jobportal.oyostate.gov.ng lori aiyelumara lati dahun fiili foomu igbanisise.

 

Foomu igbenisise naa gbodo ni number kan AMOD eyi ti yo wa loke foomu na ni apa osi.

Advertisement

Won tun so wipe eni to ba fe gba ise naa gbodo wa laarin omo odun meedogbon ati adoota ti ara re da pe.

 

Eni naa gbodo lo ile iwosan eyi ti ijoba fi owo si fun ayewo ipo ilera won o si gbodo ni oniduro.

Advertisement

Olayinka so wipe eni ti ko ba te le ilana wonyin ni yio kuna lati gba ise ati wipe awon iko amotekun ti won ba ti le kuro lenu ise fun asemose kan tabi omiran ko ni eto lati kowe fun ise naa.

 

Awon ti won ba mu fun ise naa ni won yo da si inu igbo (forest)lati see abo fun agbegbe naa.

 

Summary translation 

The Governor Seyi Makinde-led administration in Oyo state is set to recruit new Amotekun operatives that will be deployed in the forest (Forest Rangers) to combat various forms of criminalities there especially kidnapping.

 

This information is made available to newsmen recently by Amotekun Corps commander in the state Olayinka Olayanju.

 

Those eligible are healthy people with age ranging from 25 to 50 years.

 

Interested persons can access the form via www.jobportal.oyostate.gov.ng.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *